Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 12:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olukọni, Mose kọwe fun wa pe, Bi arakunrin ẹnikan ba kú, ti o ba si fi aya silẹ, ti kò si fi ọmọ silẹ, ki arakunrin rẹ̀ ki o ṣu aya rẹ̀ lopó, ki o si gbe iru-ọmọ dide fun arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:19 ni o tọ