Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 12:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si de, nwọn wi fun u pe, Olukọni, awa mọ̀ pe olotitọ ni iwọ bẹ̃ni iwọ kì iwoju ẹnikẹni: nitori iwọ kì iṣe ojuṣãju enia, ṣugbọn iwọ nkọ́ni li ọ̀na Ọlọrun li otitọ: O tọ́ lati mã san owode fun Kesari, tabi kò tọ́?

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:14 ni o tọ