Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 11:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lõtọ ni mo wi fun nyin, Ẹnikẹni ti o ba wi fun òke yi pe, Ṣidi, ki o si bọ sinu okun; ti kò ba si ṣiyemeji li ọkàn rẹ̀, ṣugbọn ti o ba gbagbọ́ pe ohun ti on wi yio ṣẹ, yio ri bẹ̃ fun u.

Ka pipe ipin Mak 11

Wo Mak 11:23 ni o tọ