Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 11:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn akọwe ati awọn olori alufa si gbọ́, nwọn si nwá ọ̀na bi nwọn o ti ṣe pa a run: nitori nwọn bẹ̀ru rẹ̀, nitori ẹnu yà gbogbo ijọ enia si ẹkọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Mak 11

Wo Mak 11:18 ni o tọ