Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 10:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Ọmọ-enia tikalarẹ̀ kò ti wá ki a ba mã ṣe iranṣẹ fun, bikoṣe lati mã ṣe iranṣẹ funni, ati lati fi ẹmi rẹ̀ ṣe irapada fun ọ̀pọlọpọ enia.

Ka pipe ipin Mak 10

Wo Mak 10:45 ni o tọ