Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 10:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnu si yà awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si ọ̀rọ rẹ̀. Ṣugbọn Jesu si tun dahùn wi fun wọn pe, Ẹnyin ọmọ, yio ti ṣoro to fun awọn ti o gbẹkẹle ọrọ̀ lati wọ̀ ijọba Ọlọrun!

Ka pipe ipin Mak 10

Wo Mak 10:24 ni o tọ