Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 10:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jesu sì wò o, o fẹràn rẹ̀, o si wi fun u pe, Ohun kan li o kù ọ kù: lọ tà ohunkohun ti o ni ki o si fifun awọn talakà, iwọ ó si ni iṣura li ọrun: si wá, gbé agbelebu, ki o si mã tọ̀ mi lẹhin.

Ka pipe ipin Mak 10

Wo Mak 10:21 ni o tọ