Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luk 8:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Igbagbọ́ nyin dà? Bi ẹ̀ru ti mba gbogbo wọn, ti hà si nṣe wọn, nwọn mbi ara wọn pe, irú ọkunrin kili eyi! nitori o ba ẹfufu on riru omi wi, nwọn si gbọ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Luk 8

Wo Luk 8:25 ni o tọ