Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luk 6:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbé ni fun nyin, nigbati gbogbo enia ba nsọrọ nyin ni rere! nitori bẹ̃ gẹgẹ li awọn baba wọn ṣe si awọn eke woli.

Ka pipe ipin Luk 6

Wo Luk 6:26 ni o tọ