Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luk 20:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si di akokò, o rán ọmọ-ọdọ rẹ̀ kan si awọn àgbẹ na, ki nwọn ki o le fun u ninu eso ọgba ajara na: ṣugbọn awọn àgbẹ lù u, nwọn si rán a pada lọwọ ofo.

Ka pipe ipin Luk 20

Wo Luk 20:10 ni o tọ