Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kol 4:13-15 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Nitori mo jẹri rẹ̀ pe, o ni itara pupọ fun nyin, ati fun awọn ti o wà ni Laodikea, ati awọn ti o wà ni Hierapoli.

14. Luku, oniṣegun olufẹ, ati Dema ki nyin.

15. Ẹ kí awọn ará ti o wà ni Laodikea, ati Nimfa, ati ijọ ti o wà ni ile rẹ̀.

Ka pipe ipin Kol 4