Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kol 1:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nipasẹ rẹ̀ lati bá ohun gbogbo lajà, lẹhin ti o ti fi ẹjẹ agbelebu rẹ̀ pari ija; mo ni, nipasẹ rẹ̀, nwọn iba ṣe ohun ti mbẹ li aiye, tabi ohun ti mbẹ li ọrun.

Ka pipe ipin Kol 1

Wo Kol 1:20 ni o tọ