Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 9:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina o dahùn o si wipe, Bi ẹlẹṣẹ ni, emi kò mọ̀: ohun kan ni mo mọ̀, pe mo ti fọju ri, mo riran nisisiyi.

Ka pipe ipin Joh 9

Wo Joh 9:25 ni o tọ