Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 7:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe kò si ẹnikẹni ti iṣe ohunkohun nikọ̀kọ, ti on tikararẹ̀ si nfẹ ki a mọ̀ on ni gbangba. Bi iwọ ba nṣe nkan wọnyi, fi ara rẹ hàn fun araiye.

Ka pipe ipin Joh 7

Wo Joh 7:4 ni o tọ