Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 7:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọ̀pọ ninu ijọ enia si gbà a gbọ́, nwọn si wipe, Nigbati Kristi na ba de, yio ha ṣe iṣẹ àmi jù wọnyi lọ, ti ọkunrin yi ti ṣe?

Ka pipe ipin Joh 7

Wo Joh 7:31 ni o tọ