Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 7:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa mọ̀ ibi ti ọkunrin yi gbé ti wá: ṣugbọn nigbati Kristi ba de, kò si ẹniti yio mọ̀ ibiti o gbé ti wà.

Ka pipe ipin Joh 7

Wo Joh 7:27 ni o tọ