Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 6:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi si ni ifẹ Baba ti o rán mi, pe ohun gbogbo ti o fifun mi, ki emi ki o máṣe sọ ọkan nù ninu wọn, ṣugbọn ki emi ki o le ji wọn dide nikẹhin ọjọ.

Ka pipe ipin Joh 6

Wo Joh 6:39 ni o tọ