Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 4:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina nigbati o de Galili, awọn ara Galili gbà a, nitoriti nwọn ti ri ohun gbogbo ti o ṣe ni Jerusalemu nigba ajọ; nitori awọn tikarawọn lọ si ajọ pẹlu.

Ka pipe ipin Joh 4

Wo Joh 4:45 ni o tọ