Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 21:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Ẹ sọ àwọn si apa ọtùn ọkọ̀, ẹnyin ó si ri. Nitorina nwọn sọ ọ, nwọn kò si le fà a jade nitori ọpọ ẹja.

Ka pipe ipin Joh 21

Wo Joh 21:6 ni o tọ