Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O tún wi fun u nigba keji pe, Simoni, ọmọ Jona, iwọ fẹ mi bi? O wi fun u pe, Bẹ̃ni Oluwa; iwọ mọ̀ pe, mo fẹràn rẹ. O wi fun u pe, Mã bọ́ awọn agutan mi.

Ka pipe ipin Joh 21

Wo Joh 21:16 ni o tọ