Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 20:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn ọmọ-ẹhin iyokù wi fun u pe, Awa ti ri Oluwa. Ṣugbọn o wi fun wọn pe, Bikoṣepe mo ba ri àpá iṣo li ọwọ́ rẹ̀ ki emi ki o si fi ika mi si àpá iṣó na, ki emi ki o si fi ọwọ́ mi si ìha rẹ̀, emi kì yio gbagbó.

Ka pipe ipin Joh 20

Wo Joh 20:25 ni o tọ