Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 2:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi okùn tẹrẹ ṣe paṣan, o si lé gbogbo wọn jade kuro ninu tẹmpili, ati agutan ati malu; o si dà owo awọn onipaṣipàrọ owo nù, o si bì tabili wọn ṣubu.

Ka pipe ipin Joh 2

Wo Joh 2:15 ni o tọ