Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 19:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pilatu si tún jade, o si wi fun wọn pe, Wo o, mo mu u jade tọ̀ nyin wá, ki ẹnyin ki o le mọ̀ pe, emi kò ri ẹ̀ṣẹ kan lọwọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 19

Wo Joh 19:4 ni o tọ