Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 19:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori o jẹ ọjọ Ipalẹmọ, ki okú wọn ma bà wà lori agbelebu li ọjọ isimi, (nitori ojọ nla ni ọjọ isimi na) nitorina awọn Ju bẹ̀ Pilatu pe ki a ṣẹ egungun itan wọn, ki a si gbe wọn kuro.

Ka pipe ipin Joh 19

Wo Joh 19:31 ni o tọ