Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 19:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ọpọ awọn Ju li o kà iwe akọle yi: nitori ibi ti a gbé kàn Jesu mọ agbelebu sunmọ eti ilu: a si kọ ọ li ède Heberu, ati ti Latini, ati ti Helene.

Ka pipe ipin Joh 19

Wo Joh 19:20 ni o tọ