Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 19:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyi Pilatu nwá ọ̀na lati dá a silẹ: ṣugbọn awọn Ju kigbe, wipe, Bi iwọ ba dá ọkunrin yi silẹ, iwọ kì iṣe ọrẹ́ Kesari: ẹnikẹni ti o ba ṣe ara rẹ̀ li ọba, o sọ̀rọ òdi si Kesari.

Ka pipe ipin Joh 19

Wo Joh 19:12 ni o tọ