Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 18:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Pilatu wi fun u pe, Njẹ iwọ ha ṣe ọba bi? Jesu dahùn wipe, Iwọ wipe, ọba li emi iṣe. Nitori eyi li a ṣe bí mi, ati nitori idi eyi ni mo si ṣe wá si aiye, ki emi ki o le jẹri si otitọ. Olukuluku ẹniti iṣe ti otitọ ngbọ́ ohùn mi.

Ka pipe ipin Joh 18

Wo Joh 18:37 ni o tọ