Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 18:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina nwọn fa Jesu lati ọdọ Kaiafa lọ si ibi gbọ̀ngan idajọ: o si jẹ kùtukùtu owurọ̀; awọn tikarawọn kò wọ̀ ini gbọ̀ngàn idajọ, ki nwọn ki o má ṣe di alaimọ́, ṣugbọn ki nwọn ki o le jẹ àse irekọja.

Ka pipe ipin Joh 18

Wo Joh 18:28 ni o tọ