Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 18:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ọmọbinrin na ti nṣọ ẹnu-ọ̀na wi fun Peteru pe, Iwọ pẹlu ha ṣe ọkan ninu awọn ọmọ-ẹhin ọkunrin yi bi? O wipe, Emi kọ́.

Ka pipe ipin Joh 18

Wo Joh 18:17 ni o tọ