Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 18:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kọ́ fa a lọ sọdọ Anna; nitori on ni iṣe ana Kaiafa, ẹniti iṣe olori alufa li ọdún na.

Ka pipe ipin Joh 18

Wo Joh 18:13 ni o tọ