Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 17:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki gbogbo nwọn ki o le jẹ ọ̀kan; gẹgẹ bi iwọ, Baba, ti jẹ ninu mi, ati emi ninu rẹ, ki awọn pẹlu ki o le jẹ ọ̀kan ninu wa: ki aiye ki o le gbagbọ́ pe, iwọ li o rán mi.

Ka pipe ipin Joh 17

Wo Joh 17:21 ni o tọ