Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NKAN wọnyi ni Jesu sọ, o si gbé oju rẹ̀ soke ọrun, o si wipe, Baba, wakati na de: yìn Ọmọ rẹ logo, ki Ọmọ rẹ ki o le yìn ọ logo pẹlu:

Ka pipe ipin Joh 17

Wo Joh 17:1 ni o tọ