Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 15:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iṣe ẹnyin li o yàn mi, ṣugbọn emi li o yàn nyin, mo si fi nyin sipo, ki ẹnyin ki o le lọ, ki ẹ si so eso, ati ki eso nyin le duro; ki ohunkohun ti ẹ ba bère lọwọ Baba li orukọ mi, ki o le fi i fun nyin.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:16 ni o tọ