Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 12:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ijọ enia ninu awọn Ju li o mọ̀ pe o wà nibẹ̀: nwọn si wá, kì iṣe nitori Jesu nikan, ṣugbọn ki nwọn le ri Lasaru pẹlu, ẹniti o ti jí dide kuro ninu okú.

Ka pipe ipin Joh 12

Wo Joh 12:9 ni o tọ