Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 12:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Maria mu ororo ikunra nardi, oṣuwọn litra kan, ailabùla, olowo iyebiye, o si nfi kùn Jesu li ẹsẹ, o si nfi irun ori rẹ̀ nù ẹsẹ rẹ̀ nù: ile si kún fun õrùn ikunra na.

Ka pipe ipin Joh 12

Wo Joh 12:3 ni o tọ