Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 12:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nkan wọnyi kò tète yé awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀: ṣugbọn nigbati a ṣe Jesu logo, nigbana ni nwọn ranti pe, a kọwe nkan wọnyi niti rẹ̀, ati pe, on ni nwọn ṣe nkan wọnyi si.

Ka pipe ipin Joh 12

Wo Joh 12:16 ni o tọ