Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 11:54 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Jesu kò rìn ni gbangba larin awọn Ju mọ́; ṣugbọn o ti ibẹ̀ lọ si igberiko kan ti o sunmọ aginjù, si ilu nla ti à npè ni Efraimu, nibẹ̀ li o si wà pẹlu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 11

Wo Joh 11:54 ni o tọ