Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 10:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn Ju wá duro yi i ká, nwọn si wi fun u pe, Iwọ ó ti mu wa ṣe iyemeji pẹ to? Bi iwọ ni iṣe Kristi na, wi fun wa gbangba.

Ka pipe ipin Joh 10

Wo Joh 10:24 ni o tọ