Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 10:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikan kò gbà a lọwọ mi, ṣugbọn mo fi i lelẹ fun ara mi. Mo li agbara lati fi i lelẹ, mo si li agbara lati tún gbà a. Aṣẹ yi ni mo ti gbà lati ọdọ Baba mi wá.

Ka pipe ipin Joh 10

Wo Joh 10:18 ni o tọ