Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joh 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LÕTỌ, lõtọ ni mo wi fun nyin, Ẹniti kò ba gbà ẹnu-ọ̀na wọ̀ inu agbo agutan, ṣugbọn ti o ba gbà ibomiran gùn oke, on na li olè ati ọlọṣà.

Ka pipe ipin Joh 10

Wo Joh 10:1 ni o tọ