Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jak 5:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki o mọ̀ pe, ẹniti o ba yi ẹlẹṣẹ kan pada kuro ninu ìṣina rẹ̀, yio gbà ọkàn kan là kuro lọwọ ikú, yio si bò ọ̀pọlọpọ ẹ̀ṣẹ mọlẹ.

Ka pipe ipin Jak 5

Wo Jak 5:20 ni o tọ