Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Pet 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si jẹ ère aiṣododo, awọn ti nwọn kà a si aiye jijẹ lati mã jẹ adùn aiye li ọsán. Nwọn jẹ́ abawọn ati àbuku, nwọn njaiye ninu asè-ifẹ́ wọn nigbati nwọn ba njẹ ase pẹlu nyin;

Ka pipe ipin 2. Pet 2

Wo 2. Pet 2:13 ni o tọ