Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Pet 2:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn pãpã awọn ti ntọ̀ ara lẹhin ninu ifẹkufẹ ẽri, ti nwọn si ngàn awọn ijoye, awọn ọ̀yájú, aṣe-tinuẹni, nwọn kò bẹ̀ru ati mã sọ̀rọ ẹgan si awọn oloye.

Ka pipe ipin 2. Pet 2

Wo 2. Pet 2:10 ni o tọ