Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi yọ̀ nisisiyi, kì iṣe nitoriti a mu inu nyin bajẹ, ṣugbọn nitoriti a mu inu nyin bajẹ si ironupiwada: nitoriti a mu inu nyin bajẹ bi ẹni ìwa-bi-Ọlọrun, ki ẹnyin ki o maṣe tipasẹ wa pàdanù li ohunkohun.

Ka pipe ipin 2. Kor 7

Wo 2. Kor 7:9 ni o tọ