Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 7:15-16 Yorùbá Bibeli (YCE)

15. Iyọ́nu rẹ̀ si di pupọ̀ gidigidi si nyin, bi on ti nranti igbọran gbogbo nyin, bi ẹ ti fi ibẹru ati iwarìri tẹwọgbà a.

16. Mo yọ̀ nitoripe li ohun gbogbo mo ni igbẹkẹle ninu nyin.

Ka pipe ipin 2. Kor 7