Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 7:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, nitori ohun kanna yi ti a mu nyin banujẹ fun bi ẹni ìwa-bi-Ọlọrun, iṣọra ti o mu ba nyin ti kara to, ijirẹbẹ nyin ti tó, ani irunu, ani ibẹru, ani ifẹ gbigbona, ani itara, ani igbẹsan! Ninu ohun gbogbo ẹ ti farahan pe ara nyin mọ́ ninu ọran na.

Ka pipe ipin 2. Kor 7

Wo 2. Kor 7:11 ni o tọ