Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 2:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ninu ọ̀pọlọpọ wahalà ati arodun ọkan mi ni mo ti fi ọ̀pọlọpọ omije kọwe si nyin; kì iṣe nitori ki a le bà nyin ninu jẹ, ṣugbọn ki ẹnyin ki o le mọ̀ ifẹ ti mo ni si nyin lọpọlọpọ rekọja.

Ka pipe ipin 2. Kor 2

Wo 2. Kor 2:4 ni o tọ