Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ awa ngbadura si Ọlọrun, ki ẹnyin ki o máṣe ibikibi kan; kì iṣe nitori ki awa ki o le fi ara hàn bi awọn ti a mọ̀ daju, ṣugbọn ki ẹnyin ki o le mã ṣe eyi ti o dara, bi awa tilẹ dabi awọn ti a tanù.

Ka pipe ipin 2. Kor 13

Wo 2. Kor 13:7 ni o tọ