Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kor 12:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina emi ni inu didùn ninu ailera gbogbo, ninu ẹ̀gan gbogbo, ninu aini gbogbo, ninu inunibini gbogbo, ninu wahalà gbogbo nitori Kristi: nitori nigbati mo ba jẹ alailera, nigbana ni mo di alagbara.

Ka pipe ipin 2. Kor 12

Wo 2. Kor 12:10 ni o tọ