Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Joh 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi mo ti ni ohun pupọ̀ lati kọwe si nyin, emi kò fẹ lo tákàdá ati tàdãwa. Ṣugbọn emi ni ireti lati tọ nyin wá ati lati ba nyin sọrọ lojukoju, ki ayọ̀ nyin ki o le kún.

Ka pipe ipin 2. Joh 1

Wo 2. Joh 1:12 ni o tọ